The Quran in Yoruba - Surah Al Asr translated into Yoruba, Surah Al-Asr in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Al Asr in Yoruba - اليوربا, Verses 3 - Surah Number 103 - Page 601.
وَالْعَصْرِ (1) Allahu bura pelu akoko irole aye |
إِنَّ الْإِنسَانَ لَفِي خُسْرٍ (2) Dajudaju eniyan wa ninu ofo |
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَتَوَاصَوْا بِالْحَقِّ وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ (3) Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won so asotele ododo laaarin ara won, ti won si tun so asotele suuru laaarin ara won |