The Quran in Yoruba - Surah Humazah translated into Yoruba, Surah Al-Humazah in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Humazah in Yoruba - اليوربا, Verses 9 - Surah Number 104 - Page 601.

| وَيْلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ (1) Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni |
| الَّذِي جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُ (2) eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin) |
| يَحْسَبُ أَنَّ مَالَهُ أَخْلَدَهُ (3) O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye) |
| كَلَّا ۖ لَيُنبَذَنَّ فِي الْحُطَمَةِ (4) Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni |
| وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْحُطَمَةُ (5) Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh |
| نَارُ اللَّهِ الْمُوقَدَةُ (6) (Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere) |
| الَّتِي تَطَّلِعُ عَلَى الْأَفْئِدَةِ (7) eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo |
| إِنَّهَا عَلَيْهِم مُّؤْصَدَةٌ (8) Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata |
| فِي عَمَدٍ مُّمَدَّدَةٍ (9) (Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina) |