The Quran in Yoruba - Surah Kawthar translated into Yoruba, Surah Al-Kawthar in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Kawthar in Yoruba - اليوربا, Verses 3 - Surah Number 108 - Page 602.
إِنَّا أَعْطَيْنَاكَ الْكَوْثَرَ (1) Dajudaju Awa fun o ni opolopo oore |
فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَانْحَرْ (2) Nitori naa, kirun fun Oluwa re, ki o si gunran (fun Un) |
إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ الْأَبْتَرُ (3) Dajudaju, eni t’o n binu re, oun ni ko nii leyin |