The Quran in Yoruba - Surah Maun translated into Yoruba, Surah Al-Maun in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Maun in Yoruba - اليوربا, Verses 7 - Surah Number 107 - Page 602.
أَرَأَيْتَ الَّذِي يُكَذِّبُ بِالدِّينِ (1) So fun mi nipa eni t’o n pe Ojo Esan niro |
فَذَٰلِكَ الَّذِي يَدُعُّ الْيَتِيمَ (2) Iyen ni eni t’o n le omo-orukan danu |
وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ الْمِسْكِينِ (3) Ko si nii gbiyanju lati bo mekunnu |
فَوَيْلٌ لِّلْمُصَلِّينَ (4) Egbe ni fun awon (munaafiki) t’o n kirun; ko tumo si “ohun t’o n run eniyan”. Amo itumo “irun” ni “ohun t’o n run ese olukirun” nitori pe ti olukirun ba ti se aluwala ni o ti san gbogbo awon ese weere ti o ti fi awon orikee ara re se siwaju. Bakan naa |
الَّذِينَ هُمْ عَن صَلَاتِهِمْ سَاهُونَ (5) awon t’o n gbagbe lati kirun won ni asiko re |
الَّذِينَ هُمْ يُرَاءُونَ (6) awon t’o n se sekarimi |
وَيَمْنَعُونَ الْمَاعُونَ (7) ati pe won n hanna ohun elo (fun awon eniyan) |