The Quran in Yoruba - Surah An Nas translated into Yoruba, Surah An-Nas in Yoruba. We provide accurate translation of Surah An Nas in Yoruba - اليوربا, Verses 6 - Surah Number 114 - Page 604.

| قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ النَّاسِ (1) So pe: "Mo sa di Oluwa awon eniyan |
| مَلِكِ النَّاسِ (2) Oba awon eniyan |
| إِلَٰهِ النَّاسِ (3) Olohun awon eniyan |
| مِن شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ (4) nibi aburu (Esu) oniroyiroyi, olusaseyin (fun eni t’o ba daruko Allah) |
| الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ (5) (Esu ni) eni ti o n ko royiroyi sinu awon okan eniyan |
| مِنَ الْجِنَّةِ وَالنَّاسِ (6) (Esu naa) wa ninu alujannu ati eniyan |