وَالسَّمَاءِ وَالطَّارِقِ (1) (Allahu) bura pelu sanmo ati Toriƙ |
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الطَّارِقُ (2) Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Toriƙ |
النَّجْمُ الثَّاقِبُ (3) Irawo ti imole re n tan roro (ni ale ni) |
إِن كُلُّ نَفْسٍ لَّمَّا عَلَيْهَا حَافِظٌ (4) Ko si emi kan afi ki eso kan wa fun un (ninu awon molaika) |
فَلْيَنظُرِ الْإِنسَانُ مِمَّ خُلِقَ (5) Nitori naa, ki eniyan woye si ohun ti A fi seda re |
خُلِقَ مِن مَّاءٍ دَافِقٍ (6) Won seda re lati inu omi t’o n tu jade kookoo |
يَخْرُجُ مِن بَيْنِ الصُّلْبِ وَالتَّرَائِبِ (7) O n jade lati aarin ibadi okunrin ati awon efonha igba-aya obinrin |
إِنَّهُ عَلَىٰ رَجْعِهِ لَقَادِرٌ (8) Dajudaju Allahu ni Alagbara lori idapada re |
يَوْمَ تُبْلَى السَّرَائِرُ (9) ni ojo ti won maa se ayewo awon (ise) asepamo |
فَمَا لَهُ مِن قُوَّةٍ وَلَا نَاصِرٍ (10) Nigba naa, ko nii si agbara tabi alaranse kan fun un |
وَالسَّمَاءِ ذَاتِ الرَّجْعِ (11) Allahu bura pelu sanmo t’o n ro ojo ni odoodun |
وَالْأَرْضِ ذَاتِ الصَّدْعِ (12) O tun bura pelu ile t’o n san kankan (fun hihujade eso) |
إِنَّهُ لَقَوْلٌ فَصْلٌ (13) Dajudaju al-Ƙur’an ni oro-ipinya (laaarin ododo ati iro) |
وَمَا هُوَ بِالْهَزْلِ (14) Ki i si se awada |
إِنَّهُمْ يَكِيدُونَ كَيْدًا (15) Dajudaju won n dete gan-an |
وَأَكِيدُ كَيْدًا (16) Emi naa si n dete gan-an |
فَمَهِّلِ الْكَافِرِينَ أَمْهِلْهُمْ رُوَيْدًا (17) Nitori naa, lora fun awon alaigbagbo. Lo won lara se fun igba die |