Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tariq ayat 4 - الطَّارق - Page - Juz 30
﴿إِن كُلُّ نَفۡسٖ لَّمَّا عَلَيۡهَا حَافِظٞ ﴾
[الطَّارق: 4]
﴿إن كل نفس لما عليها حافظ﴾ [الطَّارق: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí ẹ̀mí kan àfi kí ẹ̀ṣọ́ kan wà fún un (nínú àwọn mọlāika) |