Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 1 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿كٓهيعٓصٓ ﴾
[مَريَم: 1]
﴿كهيعص﴾ [مَريَم: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kāf hā yā ‘aēn sọ̄d. ìyá ‘Īsā ('alaehi-ssọlātu wa-ssalām) Òun l’Ó ṣà á lẹ́ṣà. Tòhun ti bẹ́ẹ̀ náà ìbá tí sọ àwọn òdodo wọ̀nyẹn nípa Mọryam ìyá Jésù. Ṣebí wọ́n kúkú fi ẹnu àbùkù kan Mọryam ẹ̀dá ni àwọn mìíràn tí Allāhu fi sọrí àwọn sūrah ọ̀rọ̀ Rẹ̀. A kúkú rí sūrah Muhammad gẹ́gẹ́ bí a ṣe rí sūrah Mọryam. Àmọ́ ìyá ‘Īsā sọ sūrah l’ó máa sọ ‘Īsā tàbí ìyá rẹ̀ di olúwa àti olùgbàlà? Tàbí ṣé nítorí pé wọ́n fi orúkọ Mọryam ìyá ‘Īsā sọ sūrah l’ó sọ ‘Īsā tàbí ìyá rẹ̀ di ọlọ́hun ọmọ? Tàbí ṣé nítorí pé wọ́n fi orúkọ Mọryam ṣíṣe tí Allāhu (subhānahu wa ta'ālā) ṣe Mọryam ní ẹ̀ṣà ènìyàn àmọ́ tí Allāhu kò ṣe ìyá àti bàbá Ànábì wa bẹ́ẹ̀ tí Allāhu fi sọrí ẹbí Mọryam a kúkú rí sūrah Ƙuraeṣ |