Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 174 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَةٗۖ وَمَا كَانَ أَكۡثَرُهُم مُّؤۡمِنِينَ ﴾
[الشعراء: 174]
﴿إن في ذلك لآية وما كان أكثرهم مؤمنين﴾ [الشعراء: 174]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àmì wà nínú ìyẹn. Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò sì jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo |