Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 65 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿فَبِأَيِّ ءَالَآءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ ﴾ 
[الرَّحمٰن: 65]
﴿فبأي آلاء ربكما تكذبان﴾ [الرَّحمٰن: 65]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, èwo nínú àwọn ìdẹ̀ra Olúwa ẹ̀yin ènìyàn àti àlùjànnú ni ẹ máa pè nírọ́  |