Quran with Yoruba translation - Surah An-Nazi‘at ayat 15 - النَّازعَات - Page - Juz 30
﴿هَلۡ أَتَىٰكَ حَدِيثُ مُوسَىٰٓ ﴾
[النَّازعَات: 15]
﴿هل أتاك حديث موسى﴾ [النَّازعَات: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ (Ànábì) Mūsā ti dé ọ̀dọ̀ rẹ |