Quran with Yoruba translation - Surah Al-Inshiqaq ayat 18 - الانشِقَاق - Page - Juz 30
﴿وَٱلۡقَمَرِ إِذَا ٱتَّسَقَ ﴾
[الانشِقَاق: 18]
﴿والقمر إذا اتسق﴾ [الانشِقَاق: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mo tún búra pẹ̀lú òṣùpá nígbà tí ó bá dégbá (pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ rẹ̀) |