القرآن باللغة اليوربا - سورة الهُمَزَة مترجمة إلى اللغة اليوربا، Surah Humazah in Yoruba. نوفر ترجمة دقيقة سورة الهُمَزَة باللغة اليوربا - Yoruba, الآيات 9 - رقم السورة 104 - الصفحة 601.
وَيْلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ (1) Egbe ni fun gbogbo abuniloju-eni, abunileyin-eni |
الَّذِي جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُ (2) eni ti o ko owo jo, ti o si ka a lakatunka (lai na an fesin) |
يَحْسَبُ أَنَّ مَالَهُ أَخْلَدَهُ (3) O n lero pe dajudaju dukia re yoo mu un se gbere (nile aye) |
كَلَّا ۖ لَيُنبَذَنَّ فِي الْحُطَمَةِ (4) Rara (ko ri bee). Dajudaju won maa ku u loko sinu Hutomoh ni |
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْحُطَمَةُ (5) Ki si ni o mu o mo ohun t’o n je Hutomoh |
نَارُ اللَّهِ الْمُوقَدَةُ (6) (Ohun ni) Ina Allahu ti won n ko (t’o n jo geregere) |
الَّتِي تَطَّلِعُ عَلَى الْأَفْئِدَةِ (7) eyi ti o maa jo (eda) wo inu okan lo |
إِنَّهَا عَلَيْهِم مُّؤْصَدَةٌ (8) Dajudaju won maa ti (awon ilekun) Ina pa mo won lori patapata |
فِي عَمَدٍ مُّمَدَّدَةٍ (9) (Won maa wa) laaarin awon opo kiribiti giga (ninu Ina) |