The Quran in Yoruba - Surah Nasr translated into Yoruba, Surah An-Nasr in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Nasr in Yoruba - اليوربا, Verses 3 - Surah Number 110 - Page 603.
إِذَا جَاءَ نَصْرُ اللَّهِ وَالْفَتْحُ (1) Nigba ti aranse Allahu (lori ota esin) ati sisi ilu (Mokkah) ba sele |
وَرَأَيْتَ النَّاسَ يَدْخُلُونَ فِي دِينِ اللَّهِ أَفْوَاجًا (2) ti o si ri awon eniyan ti won wonu esin Allahu nijonijo |
فَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ وَاسْتَغْفِرْهُ ۚ إِنَّهُ كَانَ تَوَّابًا (3) nitori naa, safomo pelu idupe fun Oluwa re. Ki o si toro aforijin lodo Re. Dajudaju O n je Olugba-ironupiwada |