Quran with Yoruba translation - Surah An-Nasr ayat 3 - النَّصر - Page - Juz 30
﴿فَسَبِّحۡ بِحَمۡدِ رَبِّكَ وَٱسۡتَغۡفِرۡهُۚ إِنَّهُۥ كَانَ تَوَّابَۢا ﴾
[النَّصر: 3]
﴿فسبح بحمد ربك واستغفره إنه كان توابا﴾ [النَّصر: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí náà, ṣàfọ̀mọ́ pẹ̀lú ìdúpẹ́ fún Olúwa rẹ. Kí o sì tọrọ àforíjìn lọ́dọ̀ Rẹ̀. Dájúdájú Ó ń jẹ́ Olùgba-ìronúpìwàdà |