The Quran in Yoruba - Surah Masad translated into Yoruba, Surah Al-Masad in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Masad in Yoruba - اليوربا, Verses 5 - Surah Number 111 - Page 603.
تَبَّتْ يَدَا أَبِي لَهَبٍ وَتَبَّ (1) Owo Abu-Lahab mejeeji ti sofo. Oun naa si sofo |
مَا أَغْنَىٰ عَنْهُ مَالُهُ وَمَا كَسَبَ (2) Awon dukia re ati ohun ti o se nise (iyen, awon omo re) ko si nii ro o loro (nibi iya) |
سَيَصْلَىٰ نَارًا ذَاتَ لَهَبٍ (3) O si maa wo inu Ina elejo fofo |
وَامْرَأَتُهُ حَمَّالَةَ الْحَطَبِ (4) Ati iyawo re, alaaaru-igi-isepe elegun-un, (o maa wona) |
فِي جِيدِهَا حَبْلٌ مِّن مَّسَدٍ (5) Igba-ope ponponran maa wa ni orun re (ninu Ina) |