The Quran in Yoruba - Surah Sharh translated into Yoruba, Surah Ash-Sharh in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Sharh in Yoruba - اليوربا, Verses 8 - Surah Number 94 - Page 596.
أَلَمْ نَشْرَحْ لَكَ صَدْرَكَ (1) Se A o sipaya igba-aya re fun o bi |
وَوَضَعْنَا عَنكَ وِزْرَكَ (2) A si gbe ese re kuro lorun re |
الَّذِي أَنقَضَ ظَهْرَكَ (3) eyi ti o wo o lorun. amo ti onitoun pada gba ’Islam ibaa je pe o gba a ni owuro |
وَرَفَعْنَا لَكَ ذِكْرَكَ (4) A si gbe iranti oruko re ga fun o |
فَإِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا (5) Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira |
إِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا (6) Dajudaju idekun wa leyin inira se |
فَإِذَا فَرَغْتَ فَانصَبْ (7) Nitori naa, nigba ti o ba buse (lori okan), gbiyanju (omiran) |
وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَارْغَب (8) Odo Oluwa re si ni ki o soju kokoro oore si |