Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ikhlas ayat 4 - الإخلَاص - Page - Juz 30
﴿وَلَمۡ يَكُن لَّهُۥ كُفُوًا أَحَدُۢ ﴾
[الإخلَاص: 4]
﴿ولم يكن له كفوا أحد﴾ [الإخلَاص: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sì sí ẹnì kan tí ó jọ Ọ́." èyí ni a mọ̀ sí “rọbbu-ssamọ̄wāt wal-’ard wa mọ̄ baenahumọ̄”. Ìdí nìyí tí a ò fi túmọ̀ “Allāhu” sí “Ọlọ́hun”. Nínú èdè Yorùbá kò fẹ́ẹ̀ sí ìtúmọ̀ tí a fọkàn balẹ̀ sí fún ọ̀rọ̀-orúkọ ńlá náà “Allāhu” àfi lílo ọ̀rọ̀-orúkọ kan èyí tí àwọn Yorùbá máa ń lò ní ọjọ́un àná fún “Ọlọ́hun”. Ṣíṣe bẹ́ẹ̀ sí máa mú àríyànjiyàn lọ́wọ́. Nítorí náà |