Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 161 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿إِذۡ قَالَ لَهُمۡ أَخُوهُمۡ لُوطٌ أَلَا تَتَّقُونَ ﴾
[الشعراء: 161]
﴿إذ قال لهم أخوهم لوط ألا تتقون﴾ [الشعراء: 161]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí arákùnrin wọn, (Ànábì) Lūt, sọ pé: “Ṣé ẹ ò níí bẹ̀rù (Allāhu) ni |