Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 1 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿طسٓۚ تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡقُرۡءَانِ وَكِتَابٖ مُّبِينٍ ﴾
[النَّمل: 1]
﴿طس تلك آيات القرآن وكتاب مبين﴾ [النَّمل: 1]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tọ̄ sīn. Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah al-Ƙur’ān àti (àwọn āyah) Tírà t’ó ń yanjú ọ̀rọ̀ ẹ̀dá |