Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 78 - صٓ - Page - Juz 23
﴿وَإِنَّ عَلَيۡكَ لَعۡنَتِيٓ إِلَىٰ يَوۡمِ ٱلدِّينِ ﴾ 
[صٓ: 78]
﴿وإن عليك لعنتي إلى يوم الدين﴾ [صٓ: 78]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú ègún Mi yóò wà lórí rẹ títí di Ọjọ́ ẹ̀san  |