Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 3 - الذَّاريَات - Page - Juz 26
﴿فَٱلۡجَٰرِيَٰتِ يُسۡرٗا ﴾
[الذَّاريَات: 3]
﴿فالجاريات يسرا﴾ [الذَّاريَات: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó búra pẹ̀lú) àwọn ọkọ̀ ojú-omi t’ó ń rìn pẹ̀lú ìrọ̀rùn |