Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 48 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿وَأَنَّهُۥ هُوَ أَغۡنَىٰ وَأَقۡنَىٰ ﴾
[النَّجم: 48]
﴿وأنه هو أغنى وأقنى﴾ [النَّجم: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Òun l’Ó ń ṣe púpọ̀, Ó sì ń ṣe kékeré (oore fún ẹ̀dá) |