Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 20 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿كِتَٰبٞ مَّرۡقُومٞ ﴾
[المُطَففين: 20]
﴿كتاب مرقوم﴾ [المُطَففين: 20]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwé tí wọ́n ti kọ iṣẹ́ rere ẹ̀dá sínú rẹ̀ (tí wọ́n sì fi pamọ́ sí òkè sánmọ̀ ni ‘illiyyūn) |