Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 21 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿يَشۡهَدُهُ ٱلۡمُقَرَّبُونَ ﴾
[المُطَففين: 21]
﴿يشهده المقربون﴾ [المُطَففين: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn (mọlāika) tí wọ́n súnmọ́ Allāhu ń jẹ́rìí sí i |