The Quran in Yoruba - Surah Fatiha translated into Yoruba, Surah Al-Fatihah in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Fatiha in Yoruba - اليوربا, Verses 7 - Surah Number 1 - Page 1.
بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ (1) Ni oruko Allahu, Ajoke-aye, Asake-orun |
الْحَمْدُ لِلَّهِ رَبِّ الْعَالَمِينَ (2) Gbogbo ope n je ti Allahu, Oluwa gbogbo eda |
الرَّحْمَٰنِ الرَّحِيمِ (3) Ajoke-aye, Asake-orun |
مَالِكِ يَوْمِ الدِّينِ (4) Olukapa-ojo-esan |
إِيَّاكَ نَعْبُدُ وَإِيَّاكَ نَسْتَعِينُ (5) Iwo nikan ni a n josin fun. Odo Re nikan si ni a n wa oore si |
اهْدِنَا الصِّرَاطَ الْمُسْتَقِيمَ (6) Jijosin fun Allahu nikan soso ati diduro sinsin ninu ijosin Re itumo yii wa bee ninu surah Ali ‘Imron “Fi ese wa rinle sinu ’Islam ona taara.” Nitori naa |
صِرَاطَ الَّذِينَ أَنْعَمْتَ عَلَيْهِمْ غَيْرِ الْمَغْضُوبِ عَلَيْهِمْ وَلَا الضَّالِّينَ (7) ona awon ti O se idera fun,yato si (ona) awon eni-ibinu (iyen, awon yehudi) ati (ona) awon olusina (iyen, awon nasara) |