Quran with Yoruba translation - Surah Al-Fatihah ayat 5 - الفَاتِحة - Page - Juz 1
﴿إِيَّاكَ نَعۡبُدُ وَإِيَّاكَ نَسۡتَعِينُ ﴾
[الفَاتِحة: 5]
﴿إياك نعبد وإياك نستعين﴾ [الفَاتِحة: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ nìkan ni à ń jọ́sìn fún. Ọ̀dọ̀ Rẹ nìkan sì ni à ń wá oore sí |