The Quran in Yoruba - Surah Qariah translated into Yoruba, Surah Al-Qariah in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Qariah in Yoruba - اليوربا, Verses 11 - Surah Number 101 - Page 600.

| الْقَارِعَةُ (1) Akoko ijaya |
| مَا الْقَارِعَةُ (2) Ki ni Akoko ijaya |
| وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْقَارِعَةُ (3) Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya |
| يَوْمَ يَكُونُ النَّاسُ كَالْفَرَاشِ الْمَبْثُوثِ (4) (Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita |
| وَتَكُونُ الْجِبَالُ كَالْعِهْنِ الْمَنفُوشِ (5) awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu |
| فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَازِينُهُ (6) Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won |
| فَهُوَ فِي عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ (7) o si maa wa ninu isemi t’o yonu si |
| وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَازِينُهُ (8) Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye |
| فَأُمُّهُ هَاوِيَةٌ (9) Hawiyah si ni ibugbe re |
| وَمَا أَدْرَاكَ مَا هِيَهْ (10) Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee |
| نَارٌ حَامِيَةٌ (11) (Ohun ni) Ina gbigbona gan-an |