Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qari‘ah ayat 4 - القَارعَة - Page - Juz 30
﴿يَوۡمَ يَكُونُ ٱلنَّاسُ كَٱلۡفَرَاشِ ٱلۡمَبۡثُوثِ ﴾
[القَارعَة: 4]
﴿يوم يكون الناس كالفراش المبثوث﴾ [القَارعَة: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Òhun ni) ọjọ́ tí ènìyàn yó dà bí àfòpiná tí wọ́n fọ́nká síta |