القرآن باللغة اليوربا - سورة القارعة مترجمة إلى اللغة اليوربا، Surah Qariah in Yoruba. نوفر ترجمة دقيقة سورة القارعة باللغة اليوربا - Yoruba, الآيات 11 - رقم السورة 101 - الصفحة 600.
الْقَارِعَةُ (1) Akoko ijaya |
مَا الْقَارِعَةُ (2) Ki ni Akoko ijaya |
وَمَا أَدْرَاكَ مَا الْقَارِعَةُ (3) Ki si l’o mu o mo ohun t’o n je Akoko ijaya |
يَوْمَ يَكُونُ النَّاسُ كَالْفَرَاشِ الْمَبْثُوثِ (4) (Ohun ni) ojo ti eniyan yo da bi afopina ti won fonka sita |
وَتَكُونُ الْجِبَالُ كَالْعِهْنِ الْمَنفُوشِ (5) awon apata yo si da bi owu ti won gbon danu |
فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَازِينُهُ (6) Nitori naa, ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba te won |
فَهُوَ فِي عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ (7) o si maa wa ninu isemi t’o yonu si |
وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَازِينُهُ (8) Ni ti eni ti osuwon (ise rere) re ba si fuye |
فَأُمُّهُ هَاوِيَةٌ (9) Hawiyah si ni ibugbe re |
وَمَا أَدْرَاكَ مَا هِيَهْ (10) Ki si o mu o mo ohun t’o n je bee |
نَارٌ حَامِيَةٌ (11) (Ohun ni) Ina gbigbona gan-an |