The Quran in Yoruba - Surah Quraysh translated into Yoruba, Surah Quraysh in Yoruba. We provide accurate translation of Surah Quraysh in Yoruba - اليوربا, Verses 4 - Surah Number 106 - Page 602.
لِإِيلَافِ قُرَيْشٍ (1) (Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo |
إِيلَافِهِمْ رِحْلَةَ الشِّتَاءِ وَالصَّيْفِ (2) (Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru |
فَلْيَعْبُدُوا رَبَّ هَٰذَا الْبَيْتِ (3) Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii |
الَّذِي أَطْعَمَهُم مِّن جُوعٍ وَآمَنَهُم مِّنْ خَوْفٍ (4) Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya |