القرآن باللغة اليوربا - سورة قريش مترجمة إلى اللغة اليوربا، Surah Quraysh in Yoruba. نوفر ترجمة دقيقة سورة قريش باللغة اليوربا - Yoruba, الآيات 4 - رقم السورة 106 - الصفحة 602.

| لِإِيلَافِ قُرَيْشٍ (1) (Ike ni lati odo Allahu) fun idile Ƙuraes lati wa papo ninu aabo |
| إِيلَافِهِمْ رِحْلَةَ الشِّتَاءِ وَالصَّيْفِ (2) (Ike ni se lati odo Allahu) fun won lati wa papo ninu aabo lori irin-ajo ni igba otutu ati igba ooru |
| فَلْيَعْبُدُوا رَبَّ هَٰذَا الْبَيْتِ (3) Nitori naa, ki won josin fun Oluwa Ile (Ka‘bah) yii |
| الَّذِي أَطْعَمَهُم مِّن جُوعٍ وَآمَنَهُم مِّنْ خَوْفٍ (4) Eni ti O fun won ni jije (ni asiko) ebi. O si fi won lokan bale ninu ipaya |