Quran with Yoruba translation - Surah Quraish ayat 4 - قُرَيش - Page - Juz 30
﴿ٱلَّذِيٓ أَطۡعَمَهُم مِّن جُوعٖ وَءَامَنَهُم مِّنۡ خَوۡفِۭ ﴾
[قُرَيش: 4]
﴿الذي أطعمهم من جوع وآمنهم من خوف﴾ [قُرَيش: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí Ó fún wọn ní jíjẹ (ní àsìkò) ebi. Ó sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ nínú ìpáyà |