Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘un ayat 4 - المَاعُون - Page - Juz 30
﴿فَوَيۡلٞ لِّلۡمُصَلِّينَ ﴾
[المَاعُون: 4]
﴿فويل للمصلين﴾ [المَاعُون: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ègbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) t’ó ń kírun; kò túmọ̀ sí “ohun t’ó ń run ènìyàn”. Àmọ́ ìtúmọ̀ “ìrun” ni “ohun t’ó ń run ẹ̀ṣẹ̀ olùkírun” nítorí pé tí olùkírun bá ti ṣe àlùwàlá ni ó ti ṣan gbogbo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wẹẹrẹ tí ó ti fi àwọn oríkèé ara rẹ̀ ṣe ṣíwájú. Bákan náà |