Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 56 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَٱذۡكُرۡ فِي ٱلۡكِتَٰبِ إِدۡرِيسَۚ إِنَّهُۥ كَانَ صِدِّيقٗا نَّبِيّٗا ﴾
[مَريَم: 56]
﴿واذكر في الكتاب إدريس إنه كان صديقا نبيا﴾ [مَريَم: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ ìtàn (Ànábì) ’Idrīs tí ó wà nínú al-Ƙur’ān. Dájúdájú ó jẹ́ olódodo pọ́nńbélé, (ó sì jẹ́) Ànábì |