Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 55 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَكَانَ يَأۡمُرُ أَهۡلَهُۥ بِٱلصَّلَوٰةِ وَٱلزَّكَوٰةِ وَكَانَ عِندَ رَبِّهِۦ مَرۡضِيّٗا ﴾
[مَريَم: 55]
﴿وكان يأمر أهله بالصلاة والزكاة وكان عند ربه مرضيا﴾ [مَريَم: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó máa ń pa ará ilé rẹ̀ ní àṣẹ ìrun kíkí àti Zakāh yíyọ. Ó sì jẹ́ ẹni ìyọ́nú lọ́dọ̀ Olúwa rẹ̀ |