Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 8 - طه - Page - Juz 16
﴿ٱللَّهُ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَۖ لَهُ ٱلۡأَسۡمَآءُ ٱلۡحُسۡنَىٰ ﴾
[طه: 8]
﴿الله لا إله إلا هو له الأسماء الحسنى﴾ [طه: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu, kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun. TiRẹ̀ ni àwọn orúkọ t’ó dára jùlọ |