Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 26 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿ٱللَّهُ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ رَبُّ ٱلۡعَرۡشِ ٱلۡعَظِيمِ۩ ﴾
[النَّمل: 26]
﴿الله لا إله إلا هو رب العرش العظيم﴾ [النَّمل: 26]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu, kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun, Olúwa Ìtẹ́ ńlá |