Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 25 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿أَلَّاۤ يَسۡجُدُواْۤ لِلَّهِ ٱلَّذِي يُخۡرِجُ ٱلۡخَبۡءَ فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَيَعۡلَمُ مَا تُخۡفُونَ وَمَا تُعۡلِنُونَ ﴾
[النَّمل: 25]
﴿ألا يسجدوا لله الذي يخرج الخبء في السموات والأرض ويعلم ما تخفون﴾ [النَّمل: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni láti forí kanlẹ̀ fún Allāhu, Ẹni t’Ó ń mú ọrọ̀ t’ó pamọ́ sínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ jáde, Ó sì mọ ohun tí ẹ̀ ń fi pamọ́ àti ohun tí ẹ̀ ń ṣàfi hàn |