Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 52 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿فِي جَنَّٰتٖ وَعُيُونٖ ﴾
[الدُّخان: 52]
﴿في جنات وعيون﴾ [الدُّخان: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọn yóò wà) nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra pẹ̀lú àwọn omi ìṣẹ́lẹ̀rú (ní ìsàlẹ̀ rẹ̀) |