Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 53 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿يَلۡبَسُونَ مِن سُندُسٖ وَإِسۡتَبۡرَقٖ مُّتَقَٰبِلِينَ ﴾
[الدُّخان: 53]
﴿يلبسون من سندس وإستبرق متقابلين﴾ [الدُّخان: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yóò máa wọ aṣọ àrán fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ àti àrán t’ó nípọn; wọn yó sì máà kọjú síra wọn |