Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 44 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿وَأَنَّهُۥ هُوَ أَمَاتَ وَأَحۡيَا ﴾
[النَّجم: 44]
﴿وأنه هو أمات وأحيا﴾ [النَّجم: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Òun l’Ó ń sọ (ẹ̀dá) di òkú. Ó sì ń sọ (ẹ̀dá) di alààyè |