Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 43 - النَّجم - Page - Juz 27
﴿وَأَنَّهُۥ هُوَ أَضۡحَكَ وَأَبۡكَىٰ ﴾
[النَّجم: 43]
﴿وأنه هو أضحك وأبكى﴾ [النَّجم: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Òun l’Ó ń pa (ẹ̀dá) ní ẹ̀rín. Ó sì ń pa (ẹ̀dá) ní ẹkún |