Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rahman ayat 22 - الرَّحمٰن - Page - Juz 27
﴿يَخۡرُجُ مِنۡهُمَا ٱللُّؤۡلُؤُ وَٱلۡمَرۡجَانُ ﴾
[الرَّحمٰن: 22]
﴿يخرج منهما اللؤلؤ والمرجان﴾ [الرَّحمٰن: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òkúta oníyebíye àti ìlẹ̀kẹ̀ iyùn ń jáde nínú àwọn (odò) méjèèjì náà |