Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 27 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿وَأَصۡحَٰبُ ٱلۡيَمِينِ مَآ أَصۡحَٰبُ ٱلۡيَمِينِ ﴾
[الوَاقِعة: 27]
﴿وأصحاب اليمين ما أصحاب اليمين﴾ [الوَاقِعة: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn èrò ọwọ́ ọtún, kí ni (ó máa ti dára tó fún) àwọn èrò ọwọ́ ọtún |