Quran with Yoruba translation - Surah At-Takwir ayat 27 - التَّكوير - Page - Juz 30
﴿إِنۡ هُوَ إِلَّا ذِكۡرٞ لِّلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[التَّكوير: 27]
﴿إن هو إلا ذكر للعالمين﴾ [التَّكوير: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kí sì ni al-Ƙur’ān bí kò ṣe ìrántí fún gbogbo ẹ̀dá |