Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘la ayat 2 - الأعلى - Page - Juz 30
﴿ٱلَّذِي خَلَقَ فَسَوَّىٰ ﴾
[الأعلى: 2]
﴿الذي خلق فسوى﴾ [الأعلى: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni tí Ó dá ẹ̀dá. Ó sì ṣe (oríkèé-ríkèé rẹ̀) ní dọ́gbadọ́gba |