Quran with Yoruba translation - Surah Al-Bayyinah ayat 2 - البَينَة - Page - Juz 30
﴿رَسُولٞ مِّنَ ٱللَّهِ يَتۡلُواْ صُحُفٗا مُّطَهَّرَةٗ ﴾
[البَينَة: 2]
﴿رسول من الله يتلو صحفا مطهرة﴾ [البَينَة: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Òjíṣẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Allāhu yó (sì) máa ké àwọn tákàdá mímọ́ |