Quran with Yoruba translation - Surah Al-Masad ayat 4 - المَسَد - Page - Juz 30
﴿وَٱمۡرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلۡحَطَبِ ﴾
[المَسَد: 4]
﴿وامرأته حمالة الحطب﴾ [المَسَد: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná) |