Quran with Yoruba translation - Surah Al-Masad ayat 2 - المَسَد - Page - Juz 30
﴿مَآ أَغۡنَىٰ عَنۡهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ ﴾
[المَسَد: 2]
﴿ما أغنى عنه ماله وما كسب﴾ [المَسَد: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà) |